1. Olùkùmi Alphabets
A, B, CH, D, E, Ẹ, F, G, GB, GH, GW, H, I, J, K, KP, KW, L, M, N, O, Ọ, R, S, Ṣ, T, U, W, Y, Z
a, b, ch, d, e, ẹ, f, g, gb, gh, gw, h, i, j, k, kp, kw, l, m, n, o, ọ, r, s, ṣ, t, u, w, y, z
/a, b, ʧ, d, e, ɛ, f, g, gb, ɣ, gw, h, i, ʤ, k, kp, kw, l, m, n, o, ɔ, r, s, ʃ, t, u, w, j, z/
Table1 Olùkùmi Alphabets
a | b | ch | d | e | ẹ |
f | g | gb | gh | Gw | h |
i | j | k | kp | Kw | l |
m | n | o | ọ | r | s |
ṣ | t | u | w | y | z |
Table 2 Olùkùmi Alphabets
2. Parts of the Body
Olùkùmi English
ọ́wọ́ hand
àtálọ́wó palm of hand
ínọ́ belly
órí head
eyín teeth
ara body
irun hair
inọ́ stomach
ùdí buttocks
etín ear
imọn nose
ẹrun mouth
ozu eye
íghórẹ̀dọ̀ heart
ọnyàn breast
ọgbòdògbọ̀ thigh
ughó vagina
ókó penis
3. Eatables
Olùkùmi English
usu yam
obì kola nut
ọ̀gẹ̀dẹ̀ wẹ́rẹ́ banana
akpaka beans
ohun salt
ọbẹ soup
ùkpọ̀nràn coconut
ẹghẹn egg
ilá okra
ẹ́zá fish
4. Materials
Olùkùmi English
ugba/ughogho gourd/ vessel
òkúta stone
orúrú cotton
ẹ̀gígán basket
udo mortar
ulé house
ẹ́ní mat
aso cloth
5. Family and Relationships
Olùkùmi English
ẹnẹ person
obìnrẹn woman
oma child
ọma ọkùnrẹn son
ọmobìnrẹn daughter
ba father
yé mother
bá bá grandfather
yé yé grandmother
ọmọma grandchild
ọkùnrẹn man
olùkù friend
aya wife
ọkọ husband
ọmómànẹ́bámànẹ́ye orphan
ọmoghíyà obìnrẹn maidservant
akpẹran butcher
6. Places
Olùkùmi English
ọ́gwódé compound
ùgà room
ómí river
etin ómí river bank
ulé house
uléwé school
ọzà market
ulíwin toilet
ulimaómànẹ́ye orphanage
úlẹ́zọ́ court
7. Liquid Nouns
Olùkùmi English
ómí water
ìtọ̀ urine
ẹmọn wine
ekpo ọkpẹ oil palm
ítọ́ saliva
ẹ̀zẹ̀ blood
ómí ọnyà breast milk
8. Animals
Olùkùmi English
àgùtàn sheep
orẹfàn cow
ázá dog
ẹzò snake
ùgbẹ́n snail
eku rat
ẹ́dúwẹ́ fowl
oyin bee
ologbo cat
kpẹ́kpẹ́yẹ duck
ẹṣi horse
ẹyẹ bird
úgún vulture
ífẹ́nfẹ́n mosquito
erunlé goat
9. Plants
Olùkùmi English
gbígbẹ̀ to plant
urùngbẹ̀ plant
ọhàn bíbó orange
ijin ọ̀kpẹ̀ palm tree
10. Abstract Nouns
Olùkùmi English
rínnózú love
úbí sin
ébí hunger
ẹ̀rù fear
ọ̀ghọ̀ glory
ọ́gbán wisdom
ẹ̀kọ̀kọ̀ condition
ìtalọfọ̀ conflict
rírú consecration
batiri fate
11. Personal Pronouns
Olùkùmi English
èmi me
úwọ you
awa we
awa us
àwan they
ówún it
12. Possessive Pronouns
Olùkùmi English
tẹ́rẹ́ your
téwá ours
térẹ̀ its
13. Reciprocals
Olùkùmi English
arawa ourself
ararẹ̀ yourself
nara ownself
14. Interrogative Pronouns
Olùkùmi English
kóhùnrè what
èyẹ́nẹ who
ẹnẹ táfọ̀ whom
kátòrè which
kíyore where
kúkòre when
kóyàn why
kó how
15. Demonstrative Pronouns
Olùkùmi English
èyì this
ìwẹ̀n yí these
ẹnẹwíwẹ́n that
àwan those
16. Olukumi Numbers
i. (1-20)
Olùkùmi English
ọ̀kàn one
èzì two
ẹ̀ta three
ẹ̀rin four
ẹ̀rú five
ẹ̀fa six
èze seven
ẹ̀zọ eight
ẹ̀han nine
ẹ̀gwá ten
ọ̀kànlégwá eleven
ézìnlẹ́gwá twelve
ẹ̀talẹ́gwá thirteen
mẹ̀rẹnlémègwa fourteen
ẹ̀dógún fifteen
mẹ̀falémègwa sixteen
mèzelémègwa seventeen
mẹ̀zọ́lémègwa eighteen
ẹ̀hánlégwá nineteen
ọ́gbọ́ twenty
ii. Tens
Olùkùmi English
ẹ̀gwá ten
ọ́gbọ́ twenty
mẹ́gwáléọ́gbọ́ thirty
ózin forty
mẹ́gwàléozìn fifty
ọta sixty
mẹ́gwáléọta seventy
ọ́rẹ́n eighty
mẹ̀gwáléòrẹn ninety
orú hundred
iii. Ordinal Numbers
Olùkùmi English
òsúgwá first
òkẹ́zìn second
òkẹ́ta third
kẹ̀rẹn fourth
òkẹ́fà sixth
òkéze seventh
òkẹ́zọ eighth
òkẹ́hán ninth
òkẹ́gwá tenth
17. Time and Season
Olùkùmi English
òwúọ̀ morning
ọhán midday/afternoon
álẹ́ night
ẹ̀rín orun midnight
írálẹ́ dusk
òwúọ̀ fìrìfìrì dawn
ozùmá daylight
òní today
ọ̀la tomorrrow
àná yesterday
ọ̀túla day after tomorrow
ẹ́zẹ̀ta day before yesterday
ọ́dọ́n year
18. Colours
Olùkùmi English
fúfún white
dúdún black
kpíkpán ekpo yellow
kpúkpán red
19. Adjectives
Olùkùmi English
ègwà beautiful
gbá tall
kpúrú short
úbúẹ́gwà ugly
bẹ̀gwà horrible
lála huge
ọfọ̀tà honest
ẹ́zọ́mú guilty
ghán good
óhẹngwà attractive
20. Adverbs, Conjunctions and Prepositions
Olùkùmi English
tedé forever
óbòkwẹ́yì almost
óhúnnukàn alone
nẹ́wá behind
ídéghòba otherwise
bábà as usual
múmá furthermore
tàbí or
kànán yet
nùkò while
ùkábùsé after
òkè above
ábẹ́ below
gbẹ́ méèzìn between
kànán except
túru for